Friday 5 August 2016

KOKORO ÎLÊ GOGORO (Alawiye apa Sixteen)

Nigbâtí mo wa ni kêkêrê
Mo ma ñ yo lo si ílê gogoro
Lati rã kokoro fun a won
Aburo mi oloju kòkòrò.

Awon aburo mi á je kokoro
Won a senu roboto
Won a wa ma jo bi okoto.
Kokoro naa dun,
Mo ma n toju re sinu sòkòtò.

Ti a ba jê kokoro tan
A ma mu omi inu ìkòkò
A ma wa ma pa itan labê ígí ìrokò
Lè ba oko cocoa.

Baba mi ti lo si oko
Iya mi ti lo si odo
Ti won ba de lale
A ma lö din dódó.

Kehinde a ma soo
Nitori o je kokoro
Taiwo a ma joo
Nitori o feran ijo
Idowu ko so ododo
Nitori o je dodo iya oyinbo ati kokoro ile gogoro.

©Alagba Yommy Bishop

My first ever Yoruba piece. Inspired by Rita Oseyomon an Edo girl
("Kokoro" is an African Chin-chin from Abeokuta) while ("ile gogoro" is a tall house)

2 comments:

  1. Thankyou for this wondrous post, I am glad I observed this website on yahoo.
    gogoro s2</a

    ReplyDelete
  2. This is a great inspiring article.I am pretty much pleased with your good work.You put really very helpful information. Keep it up. Keep blogging. Looking to reading your next post.
    Gogoro Viva手機架

    ReplyDelete